is it – Yoruba Translation – Keybot Dictionary

Spacer TTN Translation Network TTN TTN Login Deutsch Français Spacer Help
Source Languages Target Languages
Keybot      11 Results   2 Domains
  2 Hits glowinc.vn  
Louis-philippe on Tub-HotTub_WellnessFASS-25Hello, Is it possible for you to deliver this Nordic bath in Quebec, Canada? Also is this a product adapted to the very cold Canadian? Thanks for your attention.
Louis Philippe on Badefass-HotTub_WellnessFASS-25Hello, Ni o ṣee ṣe fun o lati fi yi hottub ni Quebec, Canada? Ki o jẹ a dara ọja ni gidigidi tutu Canadian afefe? O ṣeun fun akiyesi rẹ.
  9 Hits www.bresor.be  
What is it that joins so many different nations and this universal configuration into a common fraternity? What makes a brother or sister in Yemen my brother or sister, and I’m from America. And makes this brother from Eritrea my brother or sister.
Kini ohun ti o so opolopo orile ede ni gbogbo agbaye yi papo ni isokan? Ki ni o ma mu ki arakunrin kan tabi arabinrin kan lati orile ede Yemen je arakunrin mi tabi arabinrin mi, mo si je omo America. Ti o ma mu ki arakunrin yi lati Eritrea je arakunrin mi. Ti o si mu arakunrin miran lati Indonesia je arakunrin mi. Ati arakunrin lati ile Afirika je arakunrin mi. Ati omiran lati Thailand, ati omiran lati Itali, Greece, Polandi, Colombia, Bolivia, Costa Rica, China, lati Spaini, lati Russia ati bebelo. Kini ohun to mu won je arakunrin tabi arabinrin mi!? Awa ti a ni eya ti o yato, ede ti o yato ati ipinlese ti o yato? Kini ohun ti o wa ninu Islam ti o so wa po di okan soso? Kini awon eya ti o se koko ninu ona ti ko ye opolopo yi sugbon ti opolopo awon eniyan aye yi n tele?